13 Nígbà tí ilẹ̀ sì mọ́, ó pe àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀; nínú wọn ni ó sì yan méjìlá, tí ó sì sọ ní àpósítélì.
Ka pipe ipin Lúùkù 6
Wo Lúùkù 6:13 ni o tọ