34 Bí ẹ̀yin bá wín fún ẹni tí ẹ̀yin ń reti láti rí gbà padà, ọpẹ́ kínni ẹ̀yin ní? Àwọn ‘ẹlẹ́sẹ̀’ pẹ̀lú ń yá ‘ẹlẹ́sẹ̀,’ kí wọn lè gba ìwọ̀n bẹ́ẹ̀ padà.
Ka pipe ipin Lúùkù 6
Wo Lúùkù 6:34 ni o tọ