Lúùkù 6:8 BMY

8 Ṣùgbọ́n ó mọ ìrò inú wọn, ó sì wí fún ọkùnrin náà tí ọwọ́ rẹ̀ rọ pé, “Dìde, kí o sì dúró láàrin.” Ó sì dìde dúró.

Ka pipe ipin Lúùkù 6

Wo Lúùkù 6:8 ni o tọ