Lúùkù 7:16 BMY

16 Ẹ̀rù sì ba gbogbo wọn: wọ́n sì yin Ọlọ́run lógo, pé, “Wòlíì ńlá dìde nínú wa,” àti pé, “Ọlọ́run sì wá bẹ àwọn ènìyàn rẹ̀ wò!”

Ka pipe ipin Lúùkù 7

Wo Lúùkù 7:16 ni o tọ