Lúùkù 7:29 BMY

29 (Gbogbo àwọn ènìyàn tí ó gbọ́ àti àwọn agbowó òde, wọ́n dá Ọlọ́run láre, nítorí tí a fi ìtẹ̀bọmi Jòhánù tẹ̀ wọn bọ mi.

Ka pipe ipin Lúùkù 7

Wo Lúùkù 7:29 ni o tọ