Lúùkù 7:42 BMY

42 Nígbà tí wọn kò sì ní ohun tí wọn ó san, ó dáríji àwọn méjèèjì. Wí nínú àwọn méjèèjì, tani yóò fẹ́ ẹ jù?”

Ka pipe ipin Lúùkù 7

Wo Lúùkù 7:42 ni o tọ