Lúùkù 8:12 BMY

12 Àwọn ti ẹ̀bá ọ̀nà ni àwọn tí ó gbọ́ nígbà náà ni Èṣù wá ó sì mú ọ̀rọ̀ náà kúrò lọ́kàn wọn, kí wọn má ba à gbàgbọ́, kí a sì gbà wọ́n là.

Ka pipe ipin Lúùkù 8

Wo Lúùkù 8:12 ni o tọ