Lúùkù 8:19 BMY

19 Nígbà náà ní ìyá rẹ̀ àti àwọn arákùnrin rẹ̀ tọ̀ ọ́ wá, wọn kò sì lè súnmọ́ ọn nítorí ọ̀pọ̀ ènìyàn.

Ka pipe ipin Lúùkù 8

Wo Lúùkù 8:19 ni o tọ