Lúùkù 8:2 BMY

2 Àti àwọn obìnrin kan, tí a ti mú láradá kúrò lọ́wọ́ àwọn ẹ̀mí búburú àti nínú àìlera wọn, Màríà tí a ń pè ní Magidalénè, lára ẹni tí ẹ̀mí èṣù méje ti jáde kúrò.

Ka pipe ipin Lúùkù 8

Wo Lúùkù 8:2 ni o tọ