Lúùkù 8:21 BMY

21 Ó sì dáhùn wí fún wọn pé, “Ìyá mi àti àwọn arákùnrin mi ni àwọn wọ̀nyí tí wọ́n ń gbọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run, tí wọ́n sì ń ṣe é.”

Ka pipe ipin Lúùkù 8

Wo Lúùkù 8:21 ni o tọ