Lúùkù 8:34 BMY

34 Nígbà tí àwọn tí n bọ́ wọn rí ohun tí ó sẹlẹ̀, wọ́n sá, wọ́n sì lọ, wọ́n sì ròyìn ní ìlú àti ní ilẹ̀ náà.

Ka pipe ipin Lúùkù 8

Wo Lúùkù 8:34 ni o tọ