Lúùkù 8:4 BMY

4 Nígbà tí ọ̀pọ̀ ìjọ ènìyàn pé jọ pọ̀, àwọn ènìyàn láti ìlú gbogbo sì tọ̀ ọ́ wá, ó fi òwe bá wọn sọ̀rọ̀ pé:

Ka pipe ipin Lúùkù 8

Wo Lúùkù 8:4 ni o tọ