Lúùkù 8:40 BMY

40 Ó sì ṣe, nígbà tí Jésù padà lọ, àwọn ènìyàn tẹ́wọ́gbà á; nítorí tí gbogbo wọn ti ń retí rẹ̀.

Ka pipe ipin Lúùkù 8

Wo Lúùkù 8:40 ni o tọ