Lúùkù 8:52 BMY

52 Gbogbo wọn sì sọkún, wọ́n pohùnréré ẹkún rẹ̀: ó sì wí fún wọn pé, “Ẹ má sọkún mọ́; kò kú, sísùn ni ó sùn.”

Ka pipe ipin Lúùkù 8

Wo Lúùkù 8:52 ni o tọ