Lúùkù 9:10 BMY

10 Nígbà tí àwọn àpósítélì sì padà dé, wọ́n ròyìn ohun gbogbo fún un tí wọ́n ti ṣe. Ó sì mú wọn, ó sì lọ sí apákan níbi ijù sí ìlú tí a ń pè ní Bẹtiṣáídà.

Ka pipe ipin Lúùkù 9

Wo Lúùkù 9:10 ni o tọ