Lúùkù 9:27 BMY

27 Ṣùgbọ́n èmi wí fún yín nítòótọ́, ẹlòmíràn dúró níhìnín yìí, tí kì yóò rí ikú, títí wọn ó fi rí ìjọba Ọlọ́run.”

Ka pipe ipin Lúùkù 9

Wo Lúùkù 9:27 ni o tọ