Lúùkù 9:3 BMY

3 Ó sì wí fún wọn pé, “Ẹ má ṣe mú nǹkan lọ fún àjò yín, ọ̀pá, tàbí àpò tàbí àkàrà, tàbí owó: bẹ́ẹ̀ ni kí ẹ̀yin má sì ṣe ní ẹ̀wù méjì.

Ka pipe ipin Lúùkù 9

Wo Lúùkù 9:3 ni o tọ