Lúùkù 9:32 BMY

32 Ṣùgbọ́n ojú Pétérù àti ti àwọn tí ń bẹ lọ́dọ̀ rẹ̀ wúwo fún oorun. Nígbà tí wọ́n sì tají, wọ́n rí ògo rẹ̀, àti ti àwọn ọkùnrin méjèèjì tí ó bá a dúró.

Ka pipe ipin Lúùkù 9

Wo Lúùkù 9:32 ni o tọ