Lúùkù 9:37 BMY

37 Ó sì ṣe, ní ijọ́ kejì, nígbà tí wọ́n sọ̀kalẹ̀ wá láti orí òkè, ọ̀pọ̀ àwọn ènìyàn wá pàdé rẹ̀.

Ka pipe ipin Lúùkù 9

Wo Lúùkù 9:37 ni o tọ