Lúùkù 9:39 BMY

39 Sì kíyèsí i, ẹ̀mí ẹ̀sù a máa mú un, a sì máa kígbe lójijì; a sì máa nà án tàntàn títí yóò fi yọ ìfófòó lẹ́nu, a máa pa á lára, kì í tilẹ̀ ń fẹ́ fi í sílẹ̀ lọ.

Ka pipe ipin Lúùkù 9

Wo Lúùkù 9:39 ni o tọ