Lúùkù 9:50 BMY

50 Jésù sì wí fún un, pé, “Má ṣe dá a lẹ́kun mọ́: nítorí ẹni tí kò bá lòdì síi yín, ó wà fún yín.”

Ka pipe ipin Lúùkù 9

Wo Lúùkù 9:50 ni o tọ