Lúùkù 9:54 BMY

54 Nígbà tí àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ Jákọ́bù àti Jòhánù sì rí i, wọ́n ní, “Olúwa wa, jẹ́ kí a pe iná láti ọ̀run wá, kí a sì pa wọ́n run, (bí Èlíjà ti ṣe?)”

Ka pipe ipin Lúùkù 9

Wo Lúùkù 9:54 ni o tọ