Lúùkù 9:57 BMY

57 Bí wọ́n ti ń lọ lọ́nà, ọkùnrin kan wí fún un pé, “Olúwa, Èmi ń fẹ́ láti máa tọ̀ ọ́ lẹ́yìn ní ibikíbi tí ìwọ bá ń lọ.”

Ka pipe ipin Lúùkù 9

Wo Lúùkù 9:57 ni o tọ