Lúùkù 9:8 BMY

8 Àwọn ẹlòmíràn sì wí pé Èlíjà ni ó farahàn; àwọn ẹlòmíràn sì wí pé, ọ̀kan nínú àwọn wòlíì àtijọ́ ni ó jíǹde.

Ka pipe ipin Lúùkù 9

Wo Lúùkù 9:8 ni o tọ