Àwọn Ọba Kinni 1:10 BM

10 Ṣugbọn kò pe Natani wolii, tabi Bẹnaya, tabi àwọn akọni ninu àwọn jagunjagun ọba, tabi Solomoni, arakunrin rẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 1

Wo Àwọn Ọba Kinni 1:10 ni o tọ