Àwọn Ọba Kinni 1:44 BM

44 Ó sì ti rán Sadoku alufaa, ati Natani wolii, ati Bẹnaya ati àwọn tí wọn ń ṣọ́ ọba pé kí wọ́n tẹ̀lé Solomoni, wọ́n sì ti gbé e gun orí ìbaaka ọba.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 1

Wo Àwọn Ọba Kinni 1:44 ni o tọ