11 Àwọn ọkọ̀ ojú omi Hiramu ọba, tí ó kó wúrà wá láti Ofiri kó ọpọlọpọ igi alimugi ati òkúta olówó iyebíye bọ̀ pẹlu.
Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 10
Wo Àwọn Ọba Kinni 10:11 ni o tọ