Àwọn Ọba Kinni 11:14 BM

14 OLUWA bá mú kí Adadi dojú ọ̀tá kọ Solomoni; Adadi yìí jẹ́ ìran ọba ní ilẹ̀ àwọn ará Edomu.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 11

Wo Àwọn Ọba Kinni 11:14 ni o tọ