Àwọn Ọba Kinni 11:28 BM

28 ó ṣe akiyesi Jeroboamu pé ó jẹ́ ọdọmọkunrin tí ó ní akitiyan. Nígbà tí Solomoni rí i bí ó ti ń ṣiṣẹ́ kára kára, ó fi ṣe olórí àwọn tí wọn ń kóni ṣiṣẹ́ tipátipá ní gbogbo agbègbè ẹ̀yà Manase ati Efuraimu.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 11

Wo Àwọn Ọba Kinni 11:28 ni o tọ