Àwọn Ọba Kinni 11:3 BM

3 Ẹẹdẹgbẹrin (700) ni àwọn obinrin ati ọmọ ọba tí Solomoni gbé níyàwó, ó sì tún ní ọọdunrun (300) obinrin mìíràn. Àwọn obinrin náà sì mú kí ọkàn rẹ̀ ṣí kúrò lọ́dọ̀ Ọlọrun.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 11

Wo Àwọn Ọba Kinni 11:3 ni o tọ