Àwọn Ọba Kinni 12:15 BM

15 Nítorí náà, ọba kò gbọ́ ti àwọn eniyan náà, nítorí pé OLUWA alára ni ó fẹ́ kí ọ̀rọ̀ yìí rí bẹ́ẹ̀, kí ọ̀rọ̀ OLUWA lè ṣẹ, tí ó bá Jeroboamu ọmọ Nebati sọ, láti ẹnu wolii Ahija ará Ṣilo.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 12

Wo Àwọn Ọba Kinni 12:15 ni o tọ