Àwọn Ọba Kinni 12:25 BM

25 Jeroboamu ọba Israẹli mọ odi yí ìlú Ṣekemu, tí ó wà ní agbègbè olókè ti Efuraimu ká, ó sì ń gbé ibẹ̀. Lẹ́yìn náà, láti Ṣekemu ó lọ mọ odi yí ìlú Penueli ká.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 12

Wo Àwọn Ọba Kinni 12:25 ni o tọ