30 Ọ̀rọ̀ yìí di ẹ̀ṣẹ̀ sí wọn lọ́rùn nítorí pé àwọn eniyan náà bẹ̀rẹ̀ sí lọ sí ìlú Bẹtẹli ati ìlú Dani láti jọ́sìn.
Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 12
Wo Àwọn Ọba Kinni 12:30 ni o tọ