Àwọn Ọba Kinni 12:5 BM

5 Rehoboamu bá dá wọn lóhùn pé, “Ẹ máa lọ ná, lẹ́yìn ọjọ́ mẹta, ẹ pada wá gbọ́ èsì.” Àwọn eniyan náà bá pada lọ.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 12

Wo Àwọn Ọba Kinni 12:5 ni o tọ