Àwọn Ọba Kinni 13:1 BM

1 OLUWA pàṣẹ fún wolii kan, ará Juda, pé kí ó lọ sí Bẹtẹli; nígbà tí ó débẹ̀ ó bá Jeroboamu tí ó dúró níwájú pẹpẹ láti sun turari.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 13

Wo Àwọn Ọba Kinni 13:1 ni o tọ