Àwọn Ọba Kinni 13:25 BM

25 Àwọn ọkunrin kan tí wọn ń kọjá lọ rí òkú ọkunrin yìí lójú ọ̀nà, ati kinniun tí ó dúró tì í. Wọ́n lọ sí ìlú Bẹtẹli níbi tí wolii àgbàlagbà náà ń gbé, wọ́n sì ròyìn ohun tí wọ́n rí fún un.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 13

Wo Àwọn Ọba Kinni 13:25 ni o tọ