Àwọn Ọba Kinni 13:34 BM

34 Ẹ̀ṣẹ̀ ni ohun tí ó ṣe yìí, ẹ̀ṣẹ̀ yìí ni ó sì run ìran rẹ̀ lórí oyè, tí wọ́n fi parun patapata lórílẹ̀ ayé.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 13

Wo Àwọn Ọba Kinni 13:34 ni o tọ