Àwọn Ọba Kinni 13:4 BM

4 Nígbà tí Jeroboamu gbọ́ ìkìlọ̀ tí wolii Ọlọrun yìí ṣe fún pẹpẹ náà, ó na ọwọ́ sí wolii náà láti ibi pẹpẹ, ó sì pàṣẹ pé kí wọ́n mú un. Lẹsẹkẹsẹ, ọwọ́ ọba bá gan, kò sì lè gbé e wálẹ̀ mọ́.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 13

Wo Àwọn Ọba Kinni 13:4 ni o tọ