Àwọn Ọba Kinni 14:13 BM

13 Gbogbo àwọn ọmọ Israẹli ni yóo ṣọ̀fọ̀ rẹ̀, wọn yóo sì sin ín, nítorí òun nìkan ni wọ́n óo sin ninu ìdílé Jeroboamu, nítorí òun nìkan ni inú OLUWA Ọlọrun Israẹli dùn sí.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 14

Wo Àwọn Ọba Kinni 14:13 ni o tọ