Àwọn Ọba Kinni 14:17 BM

17 Aya Jeroboamu bá gbéra, ó pada sí Tirisa. Bí ó ti fẹ́ wọlé ni ọmọ tí ń ṣàìsàn náà kú.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 14

Wo Àwọn Ọba Kinni 14:17 ni o tọ