Àwọn Ọba Kinni 14:26 BM

26 Ó kó gbogbo ìṣúra tí ó wà ninu ilé OLUWA ati ti ààfin ọba pátá; gbogbo apata wúrà tí Solomoni ṣe ni ó kó lọ pẹlu.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 14

Wo Àwọn Ọba Kinni 14:26 ni o tọ