Àwọn Ọba Kinni 14:31 BM

31 Rehoboamu jáde láyé, wọ́n sì sin ín sinu ibojì ọba, ní ìlú Dafidi. Naama ará Amoni ni ìyá rẹ̀. Abijamu ọmọ rẹ̀ ni ó sì gun orí oyè lẹ́yìn rẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 14

Wo Àwọn Ọba Kinni 14:31 ni o tọ