8 Mo gba ìjọba lọ́wọ́ ìdílé Dafidi, mo sì fún ọ, o kò ṣe bíi Dafidi, iranṣẹ mi, tí ó pa òfin mi mọ́, tí ó sìn mí tọkàntọkàn, tí ó sì ṣe kìkì ohun tí ó dára lójú mi.
Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 14
Wo Àwọn Ọba Kinni 14:8 ni o tọ