13 Ó yọ Maaka, ìyá baba rẹ̀, kúrò lórí oyè ìyá ọba, nítorí pé Maaka yá ère tí ó tini lójú kan fún oriṣa Aṣera. Asa gé oriṣa náà lulẹ̀, ó sì dáná sun ún ní àfonífojì Kidironi.
Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 15
Wo Àwọn Ọba Kinni 15:13 ni o tọ