Àwọn Ọba Kinni 15:28 BM

28 Ní ọdún kẹta tí Asa gorí oyè ní ilẹ̀ Juda, ni Baaṣa pa Nadabu. Baaṣa gorí oyè dípò Nadabu, ó sì di ọba ilẹ̀ Israẹli.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 15

Wo Àwọn Ọba Kinni 15:28 ni o tọ