Àwọn Ọba Kinni 15:3 BM

3 Gbogbo irú ẹ̀ṣẹ̀ tí baba Abijamu dá, ni òun náà dá. Kò fi tọkàntọkàn ṣe olóòótọ́ sí OLUWA Ọlọrun rẹ̀ bí Dafidi, baba ńlá rẹ̀ ti ṣe.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 15

Wo Àwọn Ọba Kinni 15:3 ni o tọ