Àwọn Ọba Kinni 15:33 BM

33 Ní ọdún kẹta tí Asa, ọba Juda, gorí oyè, ni Baaṣa, ọmọ Ahija, gorí oyè, ní ìlú Tirisa, ó sì di ọba gbogbo Israẹli. Ó jọba fún ọdún mẹrinlelogun.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 15

Wo Àwọn Ọba Kinni 15:33 ni o tọ