13 nítorí ẹ̀ṣẹ̀ tí Baaṣa ati Ela ọmọ rẹ̀ dá ati èyí tí wọ́n mú kí Israẹli dá, tí wọ́n mú kí OLUWA Ọlọrun Israẹli bínú nítorí oriṣa wọn.
Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 16
Wo Àwọn Ọba Kinni 16:13 ni o tọ