Àwọn Ọba Kinni 16:16 BM

16 Nígbà tí wọ́n gbọ́ pé, Simiri ti ṣọ̀tẹ̀ sí ọba ati pé ó ti pa á, lẹsẹkẹsẹ ni gbogbo Israẹli fi Omiri olórí ogun, jọba Israẹli ninu àgọ́ wọn ní ọjọ́ náà.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 16

Wo Àwọn Ọba Kinni 16:16 ni o tọ