Àwọn Ọba Kinni 16:33 BM

33 Bákan náà, ó tún ṣe oriṣa Aṣera kan. Ahabu ṣe ohun tí ó bí OLUWA Ọlọrun Israẹli ninu ju gbogbo àwọn ọba Israẹli tí wọ́n jẹ ṣáájú rẹ̀ lọ.

Ka pipe ipin Àwọn Ọba Kinni 16

Wo Àwọn Ọba Kinni 16:33 ni o tọ